Ékísódù 26:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Asọ títa márùn ún ni kí o papọ̀ mọ́ ara wọn, kí o sì ṣe bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú márùn-ún tókù.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:1-7