Ékísódù 26:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣe àgọ́ náà pẹ̀lú aṣọ títa mẹ́wàá, aṣọ ọ̀gbọ̀ olókùn wíwẹ́ àti àsọ aláró, ti elésèé àlùkò, àti ti òdòdó, pẹ̀lú àwọn kérúbù ni kí ó ṣe iṣẹ́ ọlọ́nà sí wọn.

Ékísódù 26

Ékísódù 26:1-6