Ékísódù 21:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí olówó rẹ̀ bá fún un ní aya, tí aya náà sì bímọ ọkùnrin àti obìnrin, aya àti àwọn ọmọ rẹ̀ yóò jẹ́ ti olówó rẹ̀, yóò sì lọ ní òmìnira ní òun nìkan.

Ékísódù 21

Ékísódù 21:1-5