Ékísódù 21:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Bí ìwọ̀fà náà bá sọ gbangba pé, mo fẹ́ràn olówó mi, ìyàwó mi àti àwọn mi èmi kò sì fẹ́ ẹ́ gba òmíràn mọ́:

Ékísódù 21

Ékísódù 21:1-12