Ékísódù 14:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì rí iṣẹ́ ìyanu ńlá ti Olúwa se fún wọn lára àwọn ará Éjíbítì, àwọn ènìyàn bẹ̀rù Olúwa, wọ́n sì gba Olúwa àti Mósè ìráńṣẹ́ rẹ gbọ́.

Ékísódù 14

Ékísódù 14:25-31