Ékísódù 14:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ni ọjọ́ yìí ni Olúwa gba Ísírẹ́lì là kúrò lọ́wọ́ àwọn ará Éjíbítì; Ísírẹ́lì sì rí òkú àwọn ará Éjíbítì ni etí òkun.

Ékísódù 14

Ékísódù 14:24-31