Ékísódù 15:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ orin yìí sí Olúwa:Èmi yóò kọrin sí Olúwa,nítorí òun pọ̀ ní ògo.Ẹsin àti ẹni tí ó gùn unni ó ti sọ sínú òkun.

Ékísódù 15

Ékísódù 15:1-6