Deutarónómì 9:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí bẹ́ẹ̀ kọ́, orílẹ̀ èdè tí ìwọ ti mú wa jáde wá yóò wí pé, ‘Torí pé Olúwa kò lè mú wọn lọ sí ilẹ̀ náà tí ó ti ṣèlérí fún wọn, àti pé ó ti kórìíra wọn, ni ó fi mú wọn jáde láti pa wọ́n ní ihà.’

Deutarónómì 9

Deutarónómì 9:26-29