Deutarónómì 8:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí pé Olúwa Ọlọ́run yín ń mú un yín bọ̀ wá sí ilẹ̀ rere ilẹ̀ tí ó kún fún odò àti ibú omi, pẹ̀lú àwọn ìsun tí ń ṣàn jáde láti orí òkè àti pẹ̀tẹ́lẹ̀.

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:5-16