Ilẹ̀ tí ó kún fún jéró àti ọkà bálì, tí ó sì kún fún àjàrà àti igi ọ̀pọ̀tọ́, igi pómégíránátì, òróró ólífì àti oyin.