Deutarónómì 8:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí èyí, ẹ gbọdọ̀ pa òfin Olúwa Ọlọ́run yín mọ́, nípa rínrìn ní ọ̀nà rẹ̀, àti bíbẹ̀rù rẹ̀.

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:1-12