Deutarónómì 8:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ ṣọ́ra kí ẹ má gbàgbé Olúwa Ọlọ́run yín, nípa kíkùnà láti pa àṣẹ rẹ̀, àwọn òfin rẹ̀, àti àwọn ìlànà rẹ̀ tí mo ń fún un yín lónìí mọ́.

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:8-20