Deutarónómì 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ẹ bá ti jẹ tí ẹ sì yó tán ẹ yin Olúwa Ọlọ́run yín fún pípèṣè ilẹ̀ rere fún un yín.

Deutarónómì 8

Deutarónómì 8:7-11