Deutarónómì 4:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

torí pé ó fẹ́ràn àwọn baba ńlá yín, ó sì yan àwọn ọmọ wọn ní ipò lẹ́yìn wọn. Nípa ìwà láàyè àti nípa agbára ńlá rẹ̀ ni ó fi mú un yín kúrò ní Éjíbítì.

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:34-39