Deutarónómì 4:36 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jẹ́ kí ẹ gbọ́ ohùn rẹ̀ láti ọ̀run wá, láti kọ́ ọ yín. Ní aye, ó fi iná ńlá rẹ̀ hàn yín, ẹ sì gbọ́ ohùn rẹ̀ láti àárin iná wá,

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:28-39