Deutarónómì 4:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti lé àwọn orílẹ̀ èdè tí ó tóbi tí ó sì lágbára níwájú yín; láti le è mú un yín wá sí ilẹ̀ wọn kí ẹ lè jogún rẹ̀ bí ó ti rí lónìí.

Deutarónómì 4

Deutarónómì 4:30-48