Deutarónómì 27:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mósè àti àwọn àgbà Isírẹ́lì pàṣẹ fún àwọn ènìyàn pé: “Pa gbogbo àṣẹ tí mo fún ọ lónìí mọ́.

Deutarónómì 27

Deutarónómì 27:1-5