Deutarónómì 26:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì jẹ́wọ́ pé, òun yóò gbé ọ sókè ju gbogbo orílẹ̀ èdè tí òun ti dá lọ, ní ìyìn, ní òkìkí àti ní ọlá; kí ìwọ kí ó le jẹ́ ènìyàn mímọ́ sí Olúwa Ọlọ́run rẹ gẹ́gẹ́ bí òun ti ṣe ìlérí.

Deutarónómì 26

Deutarónómì 26:13-19