Deutarónómì 22:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá se alábàápàdé ìtẹ́ ẹyẹ lẹ́gbẹ̀ẹ́ ọ̀nà, bóyá lára igi tàbí lórí ilẹ̀, tí ìyá wọn sì jòkòó lórí àwọn ọmọ, tàbí lórí àwọn ẹyin, má ṣe gbé ìyá pẹ̀lú àwọn ọmọ.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:1-9