Deutarónómì 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin kò gbọdọ̀ wọ aṣọ ọkùnrin, tàbí kí ọkùnrin wọ aṣọ obìnrin, nítorí Olúwa Ọlọ́run rẹ kórìíra ẹnikẹ́ni tí ó ṣe èyí.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:1-11