Deutarónómì 22:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

O lè gbé ọmọ, ṣùgbọ́n rí i dájú pé o jọ̀wọ́ ìyá lọ́wọ́ lọ, kí ó baà lè dára fún ọ àti kí o lè ní ẹ̀mí gígùn.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:1-11