Deutarónómì 22:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ tàbí màlúù arákùnrin rẹ tí o dùbúlẹ̀ sójú ọ̀nà, má ṣe ṣàìfiyèsí i rẹ̀, ràn án lọ́wọ́ láti dìde dúró lórí ẹṣẹ̀ rẹ̀.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:3-10