Deutarónómì 22:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣe bákan náà tí o bá rí kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ arákùnrin rẹ tàbí aṣọ ìlekè tàbí ohunkóhun rẹ̀ tí ó sọnù. Má ṣe ṣe àìkíyèsí i rẹ̀.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:1-9