Deutarónómì 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ọkùnrin náà kì í bá gbé ní tòsí rẹ tàbí bí o kò bá mọ ẹni náà, mú un lọ ilé pẹ̀lú rẹ kí o sì fi pamọ́ títí yóò fi wá a wá. Nígbà náà ni kí o fi fún un.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:1-10