Deutarónómì 22:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o bá rí màlúù tàbí àgùntàn arákùnrin rẹ tí ó ń sọnù, má ṣe ṣé àìkíyèsí i rẹ̀ ṣùgbọ́n rí i dájú pé o mú padà wá fún un.

Deutarónómì 22

Deutarónómì 22:1-7