Deutarónómì 18:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo èyí ni yóò jẹ́ ìpín àwọn àlùfáà láti ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn tí ó fi akọ màlúù tàbí àgùntàn rúbọ; wọn yóò fi èjìká àti ẹ̀rẹ̀kẹ́ méjèèjì àti gbogbo inú fún àlùfáà.

Deutarónómì 18

Deutarónómì 18:1-12