Deutarónómì 18:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọn kì yóò ní ìní láàrin àwọn arákùnrin wọn; Ọlọ́run ni yóò jẹ́ ìní i tiwọn, gẹ́gẹ́ bí ó ti se ìlérí fún wọn.

Deutarónómì 18

Deutarónómì 18:1-10