Deutarónómì 18:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àkọ́so irúgbìn ọkà rẹ, ti wáìnì àti ti òróró rẹ, àti àkọ́rẹ́ irun àgùntàn rẹ ni ìwọ yóò fi fún wọn.

Deutarónómì 18

Deutarónómì 18:1-9