Deutarónómì 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí nìyí tí àwọn ẹ̀yà Léfì kò fi ní ìpín tàbí ogún kan láàrin àwọn arákùnrin wọn. Olúwa ni ogún wọn gẹ́gẹ́ bí Olúwa Ọlọ́run ti sọ fún un yín.)

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:1-14