Deutarónómì 10:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì sọ̀kalẹ̀ láti orí òkè náà, mo sì ki àwọn síléètì òkúta náà sínú àpótí tí mo ti kàn, bí Olúwa ti pàṣẹ fún mi, wọ́n sì wà níbẹ̀ di ìsinsin yìí.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:1-15