Deutarónómì 10:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kọ ọkàn yín ní ilà, (Ẹ wẹ ọkàn ẹ̀ṣẹ̀ yín mọ́) kí ẹ má sì se jẹ́ olóríkunkun mọ́ láti òní lọ.

Deutarónómì 10

Deutarónómì 10:10-17