Dáníẹ́lì 2:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

ṣùgbọ́n, Ọlọ́run kan ń bẹ ní ọ̀run tí ó ń fi àsírí hàn. Ó ti fi han ọba Nebukadinéṣárì, ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ ní ìkẹyìn ọjọ́. Àlá àti ìran tí o rí nígbà tí o dùbúlẹ̀ lórí ibùsùn rẹ ni ìwọ̀nyí:

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:22-30