Dáníẹ́lì 2:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọba, bí ìwọ ṣe ṣùn sórí ibùsùn rẹ, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn rẹ ń ro àwọn ohun tó ń bọ̀, olùfihàn àsírí ń fi ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ fún ọ.

Dáníẹ́lì 2

Dáníẹ́lì 2:21-36