Dáníẹ́lì 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì bá wọn sọ̀rọ̀, ó sì rí i pé kò sí ẹni tí ó dàbí i Dáníẹ́lì, Hananíáyà, Míṣáẹ́lì àti Ásáríyà; Nítorí náà wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣe iṣẹ́ ọba.

Dáníẹ́lì 1

Dáníẹ́lì 1:18-21