Dáníẹ́lì 1:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní òpín ìgbà tí ọba dá, pé kí a mú wọn wá sínú ààfin, olórí àwọn ìwẹ̀fà mú wọn wá ṣíwájú ọba Nebukadinésárì.

Dáníẹ́lì 1

Dáníẹ́lì 1:11-21