Dáníẹ́lì 1:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọlọ́run fún àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin mẹ́rẹ̀ẹ̀rin wọ̀nyí ní ìmọ̀ àti òyé nínú un gbogbo onírúurú ìwé àti ẹ̀kọ́ ọ wọn: Dáníẹ́lì sì ní òyé ìran àti àlá ní oríṣìíríṣìí.

Dáníẹ́lì 1

Dáníẹ́lì 1:13-21