Bí wọ́n tilẹ wa ilẹ lọ sí ìpò òkúLáti ibẹ̀ ni ọwọ́ mi yóò ti tẹ̀ wọ́nBí wọ́n tilẹ̀ gun òkè ọ̀run lọ,láti ibẹ̀ ni èmi yóò ti mú wọn sọ̀kalẹ̀.