Ámósì 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo rí Olúwa, ó dúró ní ẹ̀bá pẹpẹ, ó sì wí pé:“Lu orí àwọn àtẹ́rígbà ìlẹ̀kùnkí àwọn òpó kí ó lè mìfọ́ wọn sí orí àwọn gbogbo ènìyànàwọn tí ó sẹ́kù ni èmi yóò fi idà pa,Ẹni tí ó sálọ nínú wọn kí yóò sá gbéẸni ti ó sá àsálà nínú wọn kí yóò gbàlà.

Ámósì 9

Ámósì 9:1-9