Àìsáyà 65:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí ó wí pé, ‘Ẹ sún mẹ́yìn; ẹ má wá sọ́dọ̀ mi,nítorí mo ti jẹ́ mímọ́ jù fún un yín!’Àwọn ènìyàn bẹ́ẹ̀ jẹ́ èéfín nínú ihò imú miiná tí ń fi gbogbo ọjọ́ jó.

Àìsáyà 65

Àìsáyà 65:3-8