Àìsáyà 65:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kíyèsí i, a ti kọ ọ́ síwájúu mi:Èmi kì yóò dákẹ́, ṣùgbọ́n n ó san ánpadà lẹ́kùn ún rẹ́rẹ́;Èmi yóò san án padà ní itan wọn

Àìsáyà 65

Àìsáyà 65:1-14