Àìsáyà 65:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n ń jókòó láàrin ibojìwọ́n sì ń lo òru wọn nínú ìṣọ́ ìkọ̀kọ̀;tí wọ́n ń jẹ ẹran ẹlẹ́dẹ̀,tí ìkòkò ọbẹ̀ wọn kún fún ẹran àìmọ́;

Àìsáyà 65

Àìsáyà 65:1-13