Àìsáyà 60:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òòrùn kì yóò sì jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ní ọ̀sán mọ́,tàbí kí ìtànsán òṣùpá tún ràn sí ọ mọ́,nítorí Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ rẹ ayérayé,àti Ọlọ́run rẹ yóò jẹ́ ògo rẹ.

Àìsáyà 60

Àìsáyà 60:12-22