Àìsáyà 60:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òòrùn rẹ kì yóò sì wọ̀ mọ́,àti òṣùpá rẹ kì yóò sì wọ òòkùn mọ́; Olúwa ni yóò jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ayérayé rẹ,àti àwọn ọjọ́ arò rẹ yóò sì dópin.

Àìsáyà 60

Àìsáyà 60:15-22