Àìsáyà 60:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

A kì yóò gbọ́ nípa rògbòdìyàn ní ilẹ̀ rẹ mọ́,tàbí ìdahoro àti ìparun nínú agbègbè rẹ,ṣùgbọ́n ìwọ yóò pe ògiri rẹ ní ìgbàlààti àwọn ẹnu bodè rẹ ní ìyìn.

Àìsáyà 60

Àìsáyà 60:8-20