Àìsáyà 60:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Dípò búróǹsì, èmi ó mú wúrà wá fún ọ,àti fàdákà dípò irun Dípò igi yóò mú búróńsì wá,àti irun dípò òkúta.Èmi yóò fi àlàáfíà ṣe gómínà rẹàti òdodo gẹ́gẹ́ bí alákòóso rẹ.

Àìsáyà 60

Àìsáyà 60:7-22