Àìsáyà 54:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ríru ìbínú.Mo fi ojú pamọ́ fún ọ fún ìṣẹ́jú kan,ṣùgbọ́n pẹ̀lú àánú àìnípẹ̀kunÈmi yóò síjú àánú wò ọ́,”ni Olúwa Olùdáǹdè rẹ wí.

Àìsáyà 54

Àìsáyà 54:1-11