Àìsáyà 54:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Fún ìgbà díẹ̀ ni mo kọ̀ ọ́ sílẹ̀,ṣùgbọ́n pẹ̀lú ọkàn ìyọ́nú èmi yóòmú ọ padà wá.

Àìsáyà 54

Àìsáyà 54:1-15