Àìsáyà 54:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Sí mi, èyí dàbí i àwọn ọjọ́ Núà,nígbà tí mo búra pé àwọn omiNúà kì yóò tún bo ilẹ̀ ayé mọ́.Bẹ́ẹ̀ ni nísinsìnyìí mo ti búra láti má ṣe bínú sí ọ,bẹ́ẹ̀ ni èmi kì yóò bá ọ wí mọ́.

Àìsáyà 54

Àìsáyà 54:3-12