Àìsáyà 47:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ṣọ̀kalẹ̀, jókòó nínú eruku,wúndíá ọmọbìnrin Bábílónì;jókòó ní ilẹ̀ẹ́lẹ̀ láìsí ìtẹ́,ọmọbìnrin àwọn ará Bábílónì.A kì yóò pè ọ́ ní aláìlókun àti ẹlẹgẹ́ mọ́.

Àìsáyà 47

Àìsáyà 47:1-10