Àìsáyà 46:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi ń mú òdodo mi bọ̀ nítòsí,kò tilẹ̀ jìnnà rárá;àti ìgbàlà mi ni a kì yóò dádúró.Èmi yóò fún Ṣíhónì ní ìgbàlàògo mi fún Ísírẹ́lì.

Àìsáyà 46

Àìsáyà 46:8-13